Become a KPR member, and enjoy cheaper prices immediately. Register here.
Ada KPR sile ni ona eto ni odun 2000 ni ilu Slovakia ni Ipin awonorile ede Eropu; Laisegbe, An pese awon irugbin ati Eweko lati gbogbo agbaye lati odun 1998.
Ilakaka wa dalori siso awon agbe po kakiri agbaye lati orisirisi awon agbegbe ifokansi lati seda orile ifinkanpamo si nla awon irugbin ati eweko (Ile ifowopamo irugbin ati eweko KPR) lati gbogbo agbaye.
Nisisiyi, ani eka mefa (6) (Slovakia, Czechia, Australia, India, Thailand, South Africa and Tanzania) ati ogorun meji (200) Alabasisepo ati awon oluko irugbin jo kakiri agbaye.
Lenujo meta yi ani anfani lati ko ati pese egberun mewa (10,000) oniruru eya eweko kakiri agbaye.
Tio ba nwa ohunkohun, Owa ni ibi tio ye! Bio tie je pe ako ni gbogbo eweko ninu asunwon wa bayi, sugbon anpeka si lojojumo, lese ese, ni irugbin si irugbin, ni eweko si eweko. Agbagbo pe ni aipe aole pese ohun kohun!
Fún títà tó ju 10 000 àwọn irúgbin ati ohun ọ̀gbìn kákur àgbàlá ayé-ọ̀pẹ́,síkáàdí,àwọn igi kékèkèé tójé àjèjí tó máa n dàgbà láàrín yìnyín àti àwọn igi-nlá,igi tútù,ọlómi nínú,ohun ọ̀gbìn,tó n je koríko,àwọn ohun ọ̀gbìn ọlọ́dún kan,àwọn ohun ọ̀gbìn ọlọ́dún méjì àti jùbẹ́ẹ̀ lọ,àwọn ohun ọ̀gbìn ìse lọ́sọ̀ó,ewébè àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.