Become a KPR member, and enjoy cheaper prices immediately. Register here.
Ona ti o dara ju lati se ibere je nipa fifi ibere re ranse nipa ero-iletaja.
Owo re ni sisan ni owolowo fi sowo si adiresi wa ti o wa ni Czechia. Owo sisan nipa fifi ranse nipa ile ifowo pamo si apo ile ifowo pamo wa ni awon orile ede wonyi: Slovakia, Bulgaria, Croatia, Czechia, Hungary, Montenegro, Poland, Romania, Serbia
Opolopo awon ile ifowo pamo ni inu isokan awon ilu Europu n pese eto ibere fun owo orile ede si orile ede (ifowo ranse ile ifowo pamo) ninu isokan Europu (Slovakia je omo egbe Isokan Europu) lai si idiyele kankan ti ohunka ifi owo ranse ati odu IBAN ba wa. Ile ifowopamo wa ki gba owo kankan fun sisan owo lona yi.
fifi owo ranse orile ede si orile ede ni an firanse lati Czechia. Eto ifinkan ranse ti o wa labe yi wa fun siso fun o ni ekunrere. A o je ki o man ni pato iye ti yo nan o lati fi nkan ranse si orile ede re ni kete ti aba ti gba ibere re.
| Opin irin ajo | Eto ifi nkan ranse ni Euro (€) fun bibere | ||||
| Ti o to 250 g | Ti o to 500 g | Ti o to 1 kg | Ti o to 2 kg | Lafikun | |
| Ile alawo funfun Europu - Isowo Orile Ede | 4 € | 6 € | 8 € | 12 € | Ao je ki o ma |
| Aye lori ile | 4 € | 6 € | 11 € | 14 € | Ao je ki o ma |
| Aye lori eto ifiwe ranse alategun (prioritaire) | 5 € | 6 € | 12 € | 16 € | Ao je ki o ma |
| Opin irin ajo | Eto ifi nkan ranse ni Euro (€) fun bibere | ||||
| Ti o to 250 g | Ti o to 500 g | Ti o to 1 kg | Ti o to 2 kg | Lafikun | |
| Ile alawo funfun Europu - Isowo Orile Ede | 5 € | 6 € | 10 € | 14 € | Ao je ki o ma |
| Aye lori ile | 5 € | 8 € | 12 € | 15 € | Ao je ki o ma |
| Aye lori eto ifiwe ranse alategun (prioritaire) | 7 € | 9 € | 14 € | 20 € | Ao je ki o ma |
For some countries you can order Express Delivery service. Guaranteed delivery within 4 days after sending the order, online Track&Trace of the shipment, insurance included.
However, as for our experience with such services, this shiping method if often several times slower, that our standard shipping method (air mail letter or parcel). For example for Asian countries it sometimes took even 30 days to receive your order (although guaranted delivery is 4 days only!), while delivery time of the standard air mail letter / parcel to the same destination takes only 7 days. Therefore we do not recommend to use EMS services as it is much more expansive and unfortunately much more slower.
Iye awon eya ti ati pese fun tita lati odun 1998 si odun 2008

Ti aba n soro nipa oro ti an pe ni awon irugbin, oja ati ipese bi ase lo lati isin yi losi waju, ko tumo si irugbin nikan sugbon eweko, eyaara eweko pelu awon ohunkohun nipa eya eweko (Irugbin, awon eweko, gige, meristematic tissues, pollen, ati bebelo. ).
Gbogbo iye owo wa ni Euro. A tun gba owo Kč (Czech crowns), ati owo USD. Yi yipada si awon owo ti an gba gbodo se se nipa lilo eto owo sise. Ako ko owo ifi nkan ranse digba awon ohun ti owa ninu iwe awon iye. Iye wa le yato lorisirisi nitori pe asiko lorisirisi, wiwa awon eso yio da lori wiwa . ati bi idiwo ba se wa si nipa kiko ere, siseto ati ffifi pamo. Sugbon, awon iye wa yio yi pada lai so fun o. (Iwe owo yi agbe jade ni www.kpr.eu) o ju gbogbo iwe iye yoku lo. Oja yo wa nipa tita tita. Jowo lenu mo pe ye won wo, wadi, laijepe ako ni le san owo miran
Owo re gbodo wole si odo wole ki ato fi oja sowo. KPR gbodo gba owo re larin ojo medogun leyin gbigba idaniloju ibere ni KPR.
Ibere re ma di fifi sowo ni gege ti ba ti gba owo re. Ko si iduro fun oja ti o ba sonu nipo fifi sowo afi ti oba ti seto idabobo pelu wa saju fifi sowo. (Eleyi je pe owo sisan lori fifi sowo yi o lo soke.)
Ibere ti aba ti se pelu owo sisan a le pare ni pa mimo si egbe KPR.
KPR se odun meji lopolopo igba pelu idaniloju wonyi:
- Irugbin je titun, o se dada, osi le dagba.
- Irugbin ati eweko je isapejuwe tooto ati ai ni awon kokoro ajenirun.
Odun meji idaniloju wa bere lati ojo ti oba ti gba oja.
Agbodo ye gbogbo ibere wo lesekese ti aba ti gba ati isoditeni gbodo di kiko sile ati fifi ranse ki egbe KPR si ri gba larin ojo medogun ti ati gba oja .
KPR ko ni gba ifisun kankan leyin ti aba ti se irugbin basubasu, gbin, fi sowo ni ona ti ko dara, fi pamo tabi fi nkan ipese si. Mase da irugbin pada lai si iyonda wa.
Sise ibere fun oja ni onakona duro fun pe oti gba awon idiwon itaja ati awon ipo.
ATTENTION! Before placing an order find out about the plant import and phytosanitary regulations for your country. Do not import species forbidden by laws to your area. Many plants have become invasive weeds in far flung areas of the world, and while we cannot necessarily predict which plants will become invasive in which regions, most countries have lists of declared invasive weeds which people are requested not to grow, or can be prosecuted if they do grow them. Please consult your conservation authority, find out which plants you should not import and grow and take care that you do not unwittingly import any known or potential invasive aliens into your area.
When you place an order, you automatically herewith agree with the terms and conditions of the transportation company. Customers outside of the European Union: Please note that we cannot take any responsibility if your shipment is confiscated by you country due to your country's import laws, import permits or custom rules.